The Nigeria Custom service has nabbed two members of a smuggling syndicate that attacked operative of the service with series of weapons at Igbogila axis in Yewa North Local Government Area of Ogun State.
The two suspected smugglers have been arraigned before the federal High Court sitting in Oke-Mosan area, Abeokuta.
The duo of the suspected smugglers; Felarun Oluwasegun and Fakorede Jelili were charged on three count charge bordering on smuggling,evasion of payment of import duties to the Nigeria Customs Service.
Agbẹjorò Vivian Aigbadon to ń rojọ́ tako àwọn afurasi náà sọ pé ọjọ́ kọkanlelogun oṣù kejì, ọdún táa wá nínú ẹ yìí lọ́wọ́ bá afurasi onifayawo méjèèjì yìí ni agbègbè Igbogila ni apa ariwa Yewa ni Ìpínlẹ̀ ogún. Tí wọn sì ṣe méjì nínú àwọn eso aṣọbode léṣe ìyẹn nígbà ti wọn jọ ń gbena woju ara wọn.
Aigbadon sọ fún ilé ẹjọ́ níwájú Adajo Adefunmilayo Demi-Ajayi pé ìwà táwọn afurasi náà wù tako abala kọkànlá, ojú ìwé kẹrindinlàádọ́ta nínú àtúnṣe ìwé òfin to gbé àjọ aṣọbode kalẹ tí ọdún 2004.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé agbẹjorò àwọn afurasi náà bẹ ile-ejo láti gba onídùúró àwọn onibara rẹ ki wọn le ṣé ìtọ́jú ara wọn. Àmọ́ adajo Demi-Ajayi tí sún igbejo náà sí ọgbọ́n ọjọ́, oṣù karùn-ún ọdún 2023 táa wá yìí, pẹ̀lú àṣẹ pe ki wọn ṣi fi àwọn afurasi náà pamọ́ sínú ọgbà àtúnṣe.
0 Comments